19 nítorí ó wu Ọlọ́run láti mú kí ohun gbogbo pé sínú rẹ̀,+ 20 kí ó sì lè tipasẹ̀ rẹ̀ mú gbogbo ohun mìíràn pa dà bá ara rẹ̀ rẹ́,+ ì báà jẹ́ àwọn ohun tó wà ní ayé tàbí àwọn ohun tó wà ní ọ̀run, bí ó ṣe fi ẹ̀jẹ̀ tó ta sílẹ̀ lórí òpó igi oró mú àlàáfíà wá.+