Àìsáyà 28:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó, màá fi òkúta+ tí a ti dán wò ṣe ìpìlẹ̀ ní Síónì,Òkúta igun ilé+ tó ṣeyebíye, ti ìpìlẹ̀ tó dájú.+ Ẹnikẹ́ni tó bá ní ìgbàgbọ́ kò ní bẹ̀rù.+
16 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó, màá fi òkúta+ tí a ti dán wò ṣe ìpìlẹ̀ ní Síónì,Òkúta igun ilé+ tó ṣeyebíye, ti ìpìlẹ̀ tó dájú.+ Ẹnikẹ́ni tó bá ní ìgbàgbọ́ kò ní bẹ̀rù.+