Ẹ́kísódù 29:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí o sun àgbò náà lódindi, jẹ́ kó rú èéfín lórí pẹpẹ. Ẹbọ sísun ló jẹ́ sí Jèhófà, olóòórùn dídùn.*+ Ó jẹ́ ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.
18 Kí o sun àgbò náà lódindi, jẹ́ kó rú èéfín lórí pẹpẹ. Ẹbọ sísun ló jẹ́ sí Jèhófà, olóòórùn dídùn.*+ Ó jẹ́ ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.