Jòhánù 15:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Èmi ni àjàrà náà; ẹ̀yin ni ẹ̀ka. Ẹnikẹ́ni tó bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, tí mo sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ẹni yìí ń so èso púpọ̀;+ torí láìsí èmi, ẹ ò lè ṣe ohunkóhun.
5 Èmi ni àjàrà náà; ẹ̀yin ni ẹ̀ka. Ẹnikẹ́ni tó bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, tí mo sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ẹni yìí ń so èso púpọ̀;+ torí láìsí èmi, ẹ ò lè ṣe ohunkóhun.