Ìṣe 28:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí náà, ó lo odindi ọdún méjì ní ilé tí òun fúnra rẹ̀ gbà,+ ó sì máa ń gba gbogbo àwọn tó bá wá sọ́dọ̀ rẹ̀ tọwọ́tẹsẹ̀, 31 ó ń wàásù Ìjọba Ọlọ́run fún wọn, ó sì ń kọ́ wọn nípa Jésù Kristi Olúwa ní fàlàlà,*+ láìsí ìdíwọ́.
30 Torí náà, ó lo odindi ọdún méjì ní ilé tí òun fúnra rẹ̀ gbà,+ ó sì máa ń gba gbogbo àwọn tó bá wá sọ́dọ̀ rẹ̀ tọwọ́tẹsẹ̀, 31 ó ń wàásù Ìjọba Ọlọ́run fún wọn, ó sì ń kọ́ wọn nípa Jésù Kristi Olúwa ní fàlàlà,*+ láìsí ìdíwọ́.