ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 10:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ìdí nìyí tí Baba fi nífẹ̀ẹ́ mi,+ torí pé mo fi ẹ̀mí* mi lélẹ̀,+ kí n lè tún rí i gbà.

  • Hébérù 2:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́ a rí Jésù, ẹni tí a mú kó rẹlẹ̀ díẹ̀ ju àwọn áńgẹ́lì lọ,+ a ti fi ògo àti ọlá dé e ládé báyìí torí ó jìyà títí ó fi kú,+ kó lè tọ́ ikú wò fún gbogbo èèyàn nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run.+

  • Hébérù 5:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọmọ ni, ó kọ́ ìgbọràn látinú ìyà tó jẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́