1 Kọ́ríńtì 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí bí gbogbo èèyàn ṣe ń kú nínú Ádámù,+ bẹ́ẹ̀ ni a ó sọ gbogbo èèyàn di ààyè nínú Kristi.+ 2 Kọ́ríńtì 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní tòótọ́, wọ́n kàn án mọ́gi* nítorí àìlera, àmọ́ ó wà láàyè nípasẹ̀ agbára Ọlọ́run.+ Lóòótọ́, àwa náà jẹ́ aláìlera pẹ̀lú rẹ̀, àmọ́ a máa wà láàyè pẹ̀lú rẹ̀+ nípasẹ̀ agbára Ọlọ́run tó wà lórí yín.+
4 Ní tòótọ́, wọ́n kàn án mọ́gi* nítorí àìlera, àmọ́ ó wà láàyè nípasẹ̀ agbára Ọlọ́run.+ Lóòótọ́, àwa náà jẹ́ aláìlera pẹ̀lú rẹ̀, àmọ́ a máa wà láàyè pẹ̀lú rẹ̀+ nípasẹ̀ agbára Ọlọ́run tó wà lórí yín.+