8 Láti ìsinsìnyí lọ, a ti fi adé òdodo + pa mọ́ dè mí, èyí tí Olúwa, onídàájọ́ òdodo,+ máa fi san mí lẹ́san ní ọjọ́ yẹn,+ síbẹ̀ kì í ṣe fún èmi nìkan, àmọ́ fún gbogbo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ ìfarahàn rẹ̀.
12Nígbà náà, torí pé a ní àwọsánmà àwọn ẹlẹ́rìí tó pọ̀ gan-an yí wa ká, ẹ jẹ́ kí àwa náà ju gbogbo ẹrù tó wúwo nù àti ẹ̀ṣẹ̀ tó máa ń wé mọ́ wa tìrọ̀rùn-tìrọ̀rùn,+ ká sì máa fi ìfaradà sá eré ìje tó wà níwájú wa,+