-
Éfésù 3:5-7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ní àwọn ìran ìṣáájú, a kò fi àṣírí yìí han àwọn ọmọ èèyàn bí a ṣe fi han àwọn wòlíì àti àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ mímọ́ nípasẹ̀ ẹ̀mí lásìkò yìí,+ 6 ìyẹn ni pé, nínú Kristi Jésù àti nípasẹ̀ ìhìn rere, kí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè lè di ajùmọ̀jogún, kí a jọ jẹ́ ẹ̀yà ara kan náà,+ kí a sì jọ pín nínú ìlérí náà. 7 Mo di òjíṣẹ́ àṣírí mímọ́ yìí* nítorí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run. Ó fún mi ní ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ yìí nígbà tó fún mi ní agbára rẹ̀.+
-