ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 8:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ó sọ pé: “Ẹ̀yin la yọ̀ǹda fún pé kí ẹ lóye àwọn àṣírí mímọ́ Ìjọba Ọlọ́run, àmọ́ àpèjúwe+ ló jẹ́ fún àwọn yòókù, kó lè jẹ́ pé, bí wọ́n tiẹ̀ ń wò, lásán ni wọ́n á máa wò àti pé bí wọ́n tiẹ̀ ń gbọ́, kó má ṣe yé wọn.+

  • 1 Kọ́ríńtì 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àmọ́ à ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n Ọlọ́run nínú àṣírí mímọ́,+ tó jẹ́ ọgbọ́n tí a fi pa mọ́, èyí tí Ọlọ́run ti yàn ṣáájú àwọn ètò àwọn nǹkan fún ògo wa.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́