Ìṣe 16:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, Pọ́ọ̀lù dé Déébè, ó sì dé Lísírà.+ Ọmọ ẹ̀yìn kan wà níbẹ̀ tó ń jẹ́ Tímótì,+ ọmọkùnrin obìnrin Júù kan tó jẹ́ onígbàgbọ́, àmọ́ Gíríìkì ni bàbá rẹ̀, 2 àwọn ará ní Lísírà àti Íkóníónì sì ròyìn rẹ̀ dáadáa.
16 Nítorí náà, Pọ́ọ̀lù dé Déébè, ó sì dé Lísírà.+ Ọmọ ẹ̀yìn kan wà níbẹ̀ tó ń jẹ́ Tímótì,+ ọmọkùnrin obìnrin Júù kan tó jẹ́ onígbàgbọ́, àmọ́ Gíríìkì ni bàbá rẹ̀, 2 àwọn ará ní Lísírà àti Íkóníónì sì ròyìn rẹ̀ dáadáa.