2 Kọ́ríńtì 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+ 2 Kọ́ríńtì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 bí ẹni tó ń kárí sọ àmọ́ à ń yọ̀ nígbà gbogbo, bí aláìní àmọ́ à ń sọ ọ̀pọ̀ di ọlọ́rọ̀, bí ẹni tí kò ní nǹkan kan, síbẹ̀ a ní ohun gbogbo.+ Fílípì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo nínú Olúwa. Lẹ́ẹ̀kan sí i, mo sọ pé, Ẹ máa yọ̀!+
4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+
10 bí ẹni tó ń kárí sọ àmọ́ à ń yọ̀ nígbà gbogbo, bí aláìní àmọ́ à ń sọ ọ̀pọ̀ di ọlọ́rọ̀, bí ẹni tí kò ní nǹkan kan, síbẹ̀ a ní ohun gbogbo.+