1 Pétérù 2:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Olúwa, ẹ fi ara yín sábẹ́ gbogbo ohun tí èèyàn dá sílẹ̀,*+ ì báà jẹ́ ọba+ torí pé ó jẹ́ aláṣẹ 14 tàbí àwọn gómìnà tó rán níṣẹ́ pé kí wọ́n fìyà jẹ àwọn aṣebi, kí wọ́n sì yin àwọn tó ń ṣe rere.+
13 Nítorí Olúwa, ẹ fi ara yín sábẹ́ gbogbo ohun tí èèyàn dá sílẹ̀,*+ ì báà jẹ́ ọba+ torí pé ó jẹ́ aláṣẹ 14 tàbí àwọn gómìnà tó rán níṣẹ́ pé kí wọ́n fìyà jẹ àwọn aṣebi, kí wọ́n sì yin àwọn tó ń ṣe rere.+