Ìfihàn 17:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n máa bá Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà jà,+ àmọ́, torí òun ni Olúwa àwọn olúwa àti Ọba àwọn ọba,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà máa ṣẹ́gun wọn.+ Bákan náà, àwọn tí a pè tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀, tí wọ́n jẹ́ àyànfẹ́ àti olóòótọ́ máa ṣẹ́gun pẹ̀lú.”+ Ìfihàn 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Orúkọ kan wà tí a kọ sára aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, àní sórí itan rẹ̀, ìyẹn Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa.+
14 Wọ́n máa bá Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà jà,+ àmọ́, torí òun ni Olúwa àwọn olúwa àti Ọba àwọn ọba,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà máa ṣẹ́gun wọn.+ Bákan náà, àwọn tí a pè tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀, tí wọ́n jẹ́ àyànfẹ́ àti olóòótọ́ máa ṣẹ́gun pẹ̀lú.”+
16 Orúkọ kan wà tí a kọ sára aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, àní sórí itan rẹ̀, ìyẹn Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa.+