-
Títù 1:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Òótọ́ ni ẹ̀rí yìí. Torí náà, máa bá wọn wí lọ́nà tó múná, kí ìgbàgbọ́ wọn lè lágbára, 14 kí wọ́n má ṣe fiyè sí ìtàn àròsọ àwọn Júù àti àṣẹ àwọn èèyàn tí wọ́n ti kúrò nínú òtítọ́.
-