-
Gálátíà 2:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Dípò bẹ́ẹ̀, nígbà tí wọ́n rí i pé a ti fi sí ìkáwọ́ mi láti sọ ìhìn rere fún àwọn tó jẹ́ aláìdádọ̀dọ́,*+ gẹ́gẹ́ bí a ṣe fi sí ìkáwọ́ Pétérù láti sọ ọ́ fún àwọn tó dádọ̀dọ́,* 8 nítorí ẹni tó fún Pétérù lágbára láti ṣe iṣẹ́ àpọ́sítélì láàárín àwọn tó dádọ̀dọ́, fún èmi náà lágbára láti ṣe é láàárín àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè,+
-