Róòmù 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fún mi, mo sọ fún gbogbo ẹni tó wà láàárín yín níbẹ̀ pé kó má ro ara rẹ̀ ju bó ṣe yẹ lọ,+ àmọ́ kó máa ronú lọ́nà tó fi hàn pé ó láròjinlẹ̀, bí Ọlọ́run ṣe fún kálukú ní ìwọ̀n ìgbàgbọ́.*+ 1 Pétérù 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé. Torí náà, kí ẹ máa ronú jinlẹ̀,+ kí ẹ sì wà lójúfò,* kí ẹ lè máa gbàdúrà.+
3 Torí nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fún mi, mo sọ fún gbogbo ẹni tó wà láàárín yín níbẹ̀ pé kó má ro ara rẹ̀ ju bó ṣe yẹ lọ,+ àmọ́ kó máa ronú lọ́nà tó fi hàn pé ó láròjinlẹ̀, bí Ọlọ́run ṣe fún kálukú ní ìwọ̀n ìgbàgbọ́.*+
7 Àmọ́ òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé. Torí náà, kí ẹ máa ronú jinlẹ̀,+ kí ẹ sì wà lójúfò,* kí ẹ lè máa gbàdúrà.+