1 Kọ́ríńtì 9:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí àwọn aláìlera, mo di aláìlera, kí n lè jèrè àwọn aláìlera.+ Mo ti di ohun gbogbo nítorí gbogbo èèyàn, kí n lè gba àwọn kan là ní gbogbo ọ̀nà tí mo bá lè gbé e gbà.
22 Nítorí àwọn aláìlera, mo di aláìlera, kí n lè jèrè àwọn aláìlera.+ Mo ti di ohun gbogbo nítorí gbogbo èèyàn, kí n lè gba àwọn kan là ní gbogbo ọ̀nà tí mo bá lè gbé e gbà.