Ìṣe 13:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Gẹ́gẹ́ bí ìlérí tó ṣe, látọ̀dọ̀ ọmọ* ọkùnrin yìí ni Ọlọ́run ti mú olùgbàlà wá fún Ísírẹ́lì, ìyẹn Jésù.+
23 Gẹ́gẹ́ bí ìlérí tó ṣe, látọ̀dọ̀ ọmọ* ọkùnrin yìí ni Ọlọ́run ti mú olùgbàlà wá fún Ísírẹ́lì, ìyẹn Jésù.+