2 Tímótì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Sa gbogbo ipá rẹ kí o lè rí ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run, kí o jẹ́ òṣìṣẹ́ tí kò ní ohunkóhun tó máa tì í lójú, tó ń lo ọ̀rọ̀ òtítọ́ bó ṣe yẹ.+
15 Sa gbogbo ipá rẹ kí o lè rí ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run, kí o jẹ́ òṣìṣẹ́ tí kò ní ohunkóhun tó máa tì í lójú, tó ń lo ọ̀rọ̀ òtítọ́ bó ṣe yẹ.+