Jòhánù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jésù dáhùn pé: “Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún ọ, tí a kò bá bí ẹnì kan látinú omi+ àti ẹ̀mí,+ kò lè wọ Ìjọba Ọlọ́run. Róòmù 8:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ àwa fúnra wa pẹ̀lú tí a ní àkọ́so, ìyẹn, ẹ̀mí náà, bẹ́ẹ̀ ni, àwa fúnra wa ń kérora nínú ara wa,+ bí a ṣe ń dúró de ìsọdọmọ+ lójú méjèèjì, ìyẹn ìtúsílẹ̀ kúrò nínú ara wa nípasẹ̀ ìràpadà. 2 Kọ́ríńtì 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, tí ẹnikẹ́ni bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi, ó ti di ẹ̀dá tuntun; àwọn ohun àtijọ́ ti kọjá lọ;+ wò ó! àwọn ohun tuntun ti dé.
5 Jésù dáhùn pé: “Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún ọ, tí a kò bá bí ẹnì kan látinú omi+ àti ẹ̀mí,+ kò lè wọ Ìjọba Ọlọ́run.
23 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ àwa fúnra wa pẹ̀lú tí a ní àkọ́so, ìyẹn, ẹ̀mí náà, bẹ́ẹ̀ ni, àwa fúnra wa ń kérora nínú ara wa,+ bí a ṣe ń dúró de ìsọdọmọ+ lójú méjèèjì, ìyẹn ìtúsílẹ̀ kúrò nínú ara wa nípasẹ̀ ìràpadà.
17 Nítorí náà, tí ẹnikẹ́ni bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi, ó ti di ẹ̀dá tuntun; àwọn ohun àtijọ́ ti kọjá lọ;+ wò ó! àwọn ohun tuntun ti dé.