24 “A ti pinnu àádọ́rin (70) ọ̀sẹ̀ fún àwọn èèyàn rẹ àti ìlú mímọ́ rẹ,+ láti fòpin sí àṣìṣe, láti pa ẹ̀ṣẹ̀ rẹ́,+ láti ṣe ètùtù torí ìṣìnà,+ láti mú òdodo tó máa wà títí láé wá,+ láti gbé èdìdì lé ìran náà àti àsọtẹ́lẹ̀+ àti láti fòróró yan Ibi Mímọ́ nínú Àwọn Ibi Mímọ́.