-
Ẹ́kísódù 1:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 ó sì sọ fún wọn pé: “Tí ẹ bá ń gbẹ̀bí+ àwọn obìnrin Hébérù, tí wọ́n sì wà lórí àpótí ìbímọ, kí ẹ pa ọmọ náà tó bá jẹ́ ọkùnrin; àmọ́ kí ẹ dá ẹ̀mí rẹ̀ sí tó bá jẹ́ obìnrin.”
-
-
Ẹ́kísódù 1:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Fáráò wá pàṣẹ fún gbogbo èèyàn rẹ̀ pé: “Ẹ ju gbogbo ọmọkùnrin Hébérù tí wọ́n bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bí sínú odò Náílì, àmọ́ kí ẹ dá ẹ̀mí gbogbo ọmọbìnrin sí.”+
-