Róòmù 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí Ìjọba Ọlọ́run kò ní nǹkan kan ṣe pẹ̀lú jíjẹ àti mímu,+ àmọ́ ó ní í ṣe pẹ̀lú òdodo àti àlàáfíà àti ayọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí mímọ́. 1 Kọ́ríńtì 8:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ oúnjẹ kọ́ ló máa mú wa sún mọ́ Ọlọ́run;+ tí a kò bá jẹun, kò bù wá kù, tí a bá sì jẹun, kò sọ wá di ẹni ńlá.+ Kólósè 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnì kankan dá yín lẹ́jọ́ lórí ohun tí ẹ̀ ń jẹ àti ohun tí ẹ̀ ń mu+ tàbí lórí àjọyọ̀ kan tí ẹ ṣe tàbí òṣùpá tuntun+ tàbí sábáàtì.+
17 Nítorí Ìjọba Ọlọ́run kò ní nǹkan kan ṣe pẹ̀lú jíjẹ àti mímu,+ àmọ́ ó ní í ṣe pẹ̀lú òdodo àti àlàáfíà àti ayọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí mímọ́.
8 Àmọ́ oúnjẹ kọ́ ló máa mú wa sún mọ́ Ọlọ́run;+ tí a kò bá jẹun, kò bù wá kù, tí a bá sì jẹun, kò sọ wá di ẹni ńlá.+
16 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnì kankan dá yín lẹ́jọ́ lórí ohun tí ẹ̀ ń jẹ àti ohun tí ẹ̀ ń mu+ tàbí lórí àjọyọ̀ kan tí ẹ ṣe tàbí òṣùpá tuntun+ tàbí sábáàtì.+