Róòmù 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí Kristi pàápàá kò ṣe ohun tó wù ú,+ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹ̀gàn ẹnu àwọn tó ń pẹ̀gàn rẹ sì ti wá sórí mi.”+ 2 Kọ́ríńtì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí náà, mò ń láyọ̀ nínú àìlera, nínú ìwọ̀sí, ní àkókò àìní, nínú inúnibíni àti ìṣòro, nítorí Kristi. Torí nígbà tí mo bá jẹ́ aláìlera, ìgbà náà ni mo di alágbára.+ 1 Pétérù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Inú yín máa dùn tí wọ́n bá ń gàn yín* nítorí orúkọ Kristi,+ torí pé ẹ̀mí ògo, àní ẹ̀mí Ọlọ́run, ti bà lé yín.
3 Nítorí Kristi pàápàá kò ṣe ohun tó wù ú,+ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹ̀gàn ẹnu àwọn tó ń pẹ̀gàn rẹ sì ti wá sórí mi.”+
10 Torí náà, mò ń láyọ̀ nínú àìlera, nínú ìwọ̀sí, ní àkókò àìní, nínú inúnibíni àti ìṣòro, nítorí Kristi. Torí nígbà tí mo bá jẹ́ aláìlera, ìgbà náà ni mo di alágbára.+
14 Inú yín máa dùn tí wọ́n bá ń gàn yín* nítorí orúkọ Kristi,+ torí pé ẹ̀mí ògo, àní ẹ̀mí Ọlọ́run, ti bà lé yín.