-
Jòhánù 17:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Mo sì ń sọ ara mi di mímọ́ nítorí wọn, kí a lè sọ àwọn náà di mímọ́ nípasẹ̀ òtítọ́.
-
-
Hébérù 10:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Torí ẹbọ kan ṣoṣo tó rú ló fi sọ àwọn tí à ń sọ di mímọ́ di pípé+ láìtún ní ṣe é mọ́ láé.
-