Mátíù 12:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Baba mi tó wà ní ọ̀run, ẹni yẹn ni arákùnrin mi, arábìnrin mi àti ìyá mi.”+ Róòmù 8:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 nítorí àwọn tó kọ́kọ́ fún ní àfiyèsí ló tún yàn ṣáájú láti jẹ́ àwòrán Ọmọ rẹ̀,+ kó lè jẹ́ àkọ́bí+ láàárín ọ̀pọ̀ arákùnrin.+
50 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Baba mi tó wà ní ọ̀run, ẹni yẹn ni arákùnrin mi, arábìnrin mi àti ìyá mi.”+
29 nítorí àwọn tó kọ́kọ́ fún ní àfiyèsí ló tún yàn ṣáájú láti jẹ́ àwòrán Ọmọ rẹ̀,+ kó lè jẹ́ àkọ́bí+ láàárín ọ̀pọ̀ arákùnrin.+