1 Kọ́ríńtì 14:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ̀yin ará, ẹ má ṣe di ọmọ kékeré nínú òye,+ àmọ́ ẹ di ọmọ kékeré ní ti ìwà burúkú;+ ẹ sì dàgbà di géńdé nínú òye.+ Éfésù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 títí gbogbo wa á fi ṣọ̀kan* nínú ìgbàgbọ́ àti nínú ìmọ̀ pípéye nípa Ọmọ Ọlọ́run, tí a ó fi di géńdé* ọkùnrin,+ tí a ó sì dàgbà dé ìwọ̀n kíkún ti Kristi.
20 Ẹ̀yin ará, ẹ má ṣe di ọmọ kékeré nínú òye,+ àmọ́ ẹ di ọmọ kékeré ní ti ìwà burúkú;+ ẹ sì dàgbà di géńdé nínú òye.+
13 títí gbogbo wa á fi ṣọ̀kan* nínú ìgbàgbọ́ àti nínú ìmọ̀ pípéye nípa Ọmọ Ọlọ́run, tí a ó fi di géńdé* ọkùnrin,+ tí a ó sì dàgbà dé ìwọ̀n kíkún ti Kristi.