-
Títù 3:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ṣeé gbára lé, mo sì fẹ́ kí o máa tẹnu mọ́ nǹkan wọ̀nyí, kí àwọn tó gba Ọlọ́run gbọ́ lè máa ronú lórí ṣíṣe iṣẹ́ rere nígbà gbogbo. Àwọn nǹkan yìí dára, wọ́n sì ń ṣeni láǹfààní.
-