Mátíù 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí náà, tí ẹ̀yin bá mọ bí ẹ ṣe ń fún àwọn ọmọ yín ní ẹ̀bùn tó dáa, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ẹni burúkú ni yín, mélòómélòó wá ni Baba yín tó wà ní ọ̀run, ohun tó dáa+ ló máa fún àwọn tó ń béèrè lọ́wọ́ rẹ̀!+
11 Torí náà, tí ẹ̀yin bá mọ bí ẹ ṣe ń fún àwọn ọmọ yín ní ẹ̀bùn tó dáa, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ẹni burúkú ni yín, mélòómélòó wá ni Baba yín tó wà ní ọ̀run, ohun tó dáa+ ló máa fún àwọn tó ń béèrè lọ́wọ́ rẹ̀!+