Gálátíà 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wọ́n ti kàn mí mọ́gi pẹ̀lú Kristi.+ Kì í ṣe èmi ló wà láàyè mọ́,+ Kristi ló wà láàyè nínú mi. Ní tòótọ́, ìgbésí ayé tí mò ń gbé báyìí nínú ara ni mò ń gbé nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Ọmọ Ọlọ́run,+ ẹni tó nífẹ̀ẹ́ mi, tó sì fi ara rẹ̀ lélẹ̀ fún mi.+ Éfésù 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, ẹ yéé ṣe bí aláìnírònú, àmọ́ ẹ máa fi òye mọ ohun tí ìfẹ́ Jèhófà* jẹ́.+
20 Wọ́n ti kàn mí mọ́gi pẹ̀lú Kristi.+ Kì í ṣe èmi ló wà láàyè mọ́,+ Kristi ló wà láàyè nínú mi. Ní tòótọ́, ìgbésí ayé tí mò ń gbé báyìí nínú ara ni mò ń gbé nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Ọmọ Ọlọ́run,+ ẹni tó nífẹ̀ẹ́ mi, tó sì fi ara rẹ̀ lélẹ̀ fún mi.+