Àìsáyà 53:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n gún un+ torí àṣìṣe wa;+Wọ́n tẹ̀ ẹ́ rẹ́ torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Ó jìyà ká lè ní àlàáfíà,+A sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.+
5 Wọ́n gún un+ torí àṣìṣe wa;+Wọ́n tẹ̀ ẹ́ rẹ́ torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Ó jìyà ká lè ní àlàáfíà,+A sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.+