2 Tímótì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìdí tí èmi náà ṣe ń jìyà àwọn nǹkan yìí nìyẹn,+ àmọ́ ojú ò tì mí.+ Torí mo mọ Ẹni tí mo gbà gbọ́, ó sì dá mi lójú pé ó lè dáàbò bo ohun tí mo fi sí ìkáwọ́ rẹ̀ títí di ọjọ́ náà.+
12 Ìdí tí èmi náà ṣe ń jìyà àwọn nǹkan yìí nìyẹn,+ àmọ́ ojú ò tì mí.+ Torí mo mọ Ẹni tí mo gbà gbọ́, ó sì dá mi lójú pé ó lè dáàbò bo ohun tí mo fi sí ìkáwọ́ rẹ̀ títí di ọjọ́ náà.+