-
Jeremáyà 11:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Jẹ́ kí n rí ẹ̀san rẹ lára wọn,
Nítorí ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹjọ́ mi lé.
-
-
Jòhánù 8:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Ṣùgbọ́n mi ò wá ògo fún ara mi;+ Ẹnì kan wà tó ń wá a, tó sì ń ṣèdájọ́.
-