24 Torí àwọn èké Kristi àti àwọn wòlíì èké+ máa dìde, wọ́n sì máa ṣe àwọn iṣẹ́ àmì àti àwọn iṣẹ́ ìyanu tó lágbára, láti ṣi àwọn àyànfẹ́ pàápàá lọ́nà,+ tó bá ṣeé ṣe.
4Àmọ́, ọ̀rọ̀ onímìísí* sọ ní kedere pé tó bá yá àwọn kan máa yẹsẹ̀ kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n á máa tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí*+ tó ń ṣini lọ́nà àti àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù,