ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hébérù 4:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí náà, ẹ jẹ́ ká sún mọ́ ìtẹ́ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí, ká sọ̀rọ̀ ní fàlàlà,+ ká lè rí àánú gbà, ká sì rí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tó máa ràn wá lọ́wọ́ ní àkókò tó tọ́.

  • 1 Jòhánù 2:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Torí náà, ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ká lè sọ̀rọ̀ ní fàlàlà  + nígbà tí a bá fi í hàn kedere, kí a má bàa fi ìtìjú kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ nígbà tó bá wà níhìn-ín.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́