Mátíù 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ẹnikẹ́ni bá gbọ́ ọ̀rọ̀ Ìjọba náà, àmọ́ tí kò yé e, ẹni burúkú náà+ á wá, á sì já ohun tí a gbìn sínú ọkàn rẹ̀ gbà lọ; èyí ni irúgbìn tó bọ́ sí etí ọ̀nà.+ Lúùkù 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Èṣù wá sọ fún un pé: “Gbogbo àṣẹ yìí àti ògo wọn ni màá fún ọ, torí a ti fi lé mi lọ́wọ́,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì wù mí ni màá fún. Jòhánù 12:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ní báyìí, à ń ṣèdájọ́ ayé yìí; ní báyìí, a máa lé alákòóso ayé yìí + jáde.+
19 Tí ẹnikẹ́ni bá gbọ́ ọ̀rọ̀ Ìjọba náà, àmọ́ tí kò yé e, ẹni burúkú náà+ á wá, á sì já ohun tí a gbìn sínú ọkàn rẹ̀ gbà lọ; èyí ni irúgbìn tó bọ́ sí etí ọ̀nà.+
6 Èṣù wá sọ fún un pé: “Gbogbo àṣẹ yìí àti ògo wọn ni màá fún ọ, torí a ti fi lé mi lọ́wọ́,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì wù mí ni màá fún.