Jòhánù 12:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ìmọ́lẹ̀ máa wà láàárín yín fúngbà díẹ̀ sí i. Ẹ rìn nígbà tí ẹ ṣì ní ìmọ́lẹ̀ náà, kí òkùnkùn má bàa borí yín; ẹnikẹ́ni tó bá ń rìn nínú òkùnkùn kò mọ ibi tí òun ń lọ.+
35 Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ìmọ́lẹ̀ máa wà láàárín yín fúngbà díẹ̀ sí i. Ẹ rìn nígbà tí ẹ ṣì ní ìmọ́lẹ̀ náà, kí òkùnkùn má bàa borí yín; ẹnikẹ́ni tó bá ń rìn nínú òkùnkùn kò mọ ibi tí òun ń lọ.+