4 Ìdí ni pé àwọn kan ti yọ́ wọlé sí àárín yín, àwọn tí Ìwé Mímọ́ ti sọ tipẹ́tipẹ́ pé ìdájọ́ ń bọ̀ sórí wọn. Wọn ò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run wa ṣe àwáwí láti máa hu ìwà àìnítìjú,+ wọ́n sì kọ Jésù Kristi, ẹnì kan ṣoṣo tó ni wá, tó sì jẹ́ Olúwa wa.+