-
2 Jòhánù 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Èyí sì ni ohun tí ìfẹ́ jẹ́, pé ká máa tẹ̀ lé àwọn àṣẹ rẹ̀.+ Àṣẹ náà nìyí, bí ẹ ṣe gbọ́ ọ láti ìbẹ̀rẹ̀, pé kí ẹ máa rìn nínú ìfẹ́.