1 Jòhánù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 A mọ̀ pé gbogbo ẹni tí a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, àmọ́ ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run* ń ṣọ́ ọ, ẹni burúkú náà ò sì lè rí i mú.*+
18 A mọ̀ pé gbogbo ẹni tí a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, àmọ́ ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run* ń ṣọ́ ọ, ẹni burúkú náà ò sì lè rí i mú.*+