Ìfihàn 22:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó sọ fún mi pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé,* òótọ́ sì ni;+ kódà, Jèhófà* Ọlọ́run tó mí sí àwọn wòlíì+ ti rán áńgẹ́lì rẹ̀ láti fi àwọn nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ láìpẹ́ han àwọn ẹrú rẹ̀.
6 Ó sọ fún mi pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé,* òótọ́ sì ni;+ kódà, Jèhófà* Ọlọ́run tó mí sí àwọn wòlíì+ ti rán áńgẹ́lì rẹ̀ láti fi àwọn nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ láìpẹ́ han àwọn ẹrú rẹ̀.