-
Jòhánù 15:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Tí ẹnikẹ́ni ò bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, a máa sọ ọ́ nù bí ẹ̀ka, á sì gbẹ. Àwọn èèyàn á kó àwọn ẹ̀ka yẹn jọ, wọ́n á sọ wọ́n sínú iná, wọ́n á sì jóná.
-