Mátíù 10:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ẹnikẹ́ni tó bá gba wòlíì torí pé ó jẹ́ wòlíì máa gba èrè wòlíì,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì gba olódodo torí pé ó jẹ́ olódodo máa gba èrè olódodo. Fílémónì 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bákan náà, mo tún fẹ́ kí o bá mi ṣètò ibi tí màá dé sí, torí mo ní ìrètí pé wọ́n á jẹ́ kí n pa dà sọ́dọ̀ yín,* lọ́lá àdúrà tí ẹ̀ ń gbà fún mi.+ 1 Pétérù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ máa ṣe ara yín lálejò láìráhùn.+
41 Ẹnikẹ́ni tó bá gba wòlíì torí pé ó jẹ́ wòlíì máa gba èrè wòlíì,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì gba olódodo torí pé ó jẹ́ olódodo máa gba èrè olódodo.
22 Bákan náà, mo tún fẹ́ kí o bá mi ṣètò ibi tí màá dé sí, torí mo ní ìrètí pé wọ́n á jẹ́ kí n pa dà sọ́dọ̀ yín,* lọ́lá àdúrà tí ẹ̀ ń gbà fún mi.+