Àìsáyà 22:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Màá sì fi kọ́kọ́rọ́ ilé Dáfídì+ sí èjìká rẹ̀. Tó bá ṣí ibì kan, ẹnì kankan ò ní tì í; tó bá sì ti ibì kan, ẹnì kankan ò ní ṣí i. Lúùkù 1:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni yìí máa jẹ́ ẹni ńlá,+ wọ́n á máa pè é ní Ọmọ Ẹni Gíga Jù Lọ,+ Jèhófà* Ọlọ́run sì máa fún un ní ìtẹ́ Dáfídì bàbá rẹ̀,+
22 Màá sì fi kọ́kọ́rọ́ ilé Dáfídì+ sí èjìká rẹ̀. Tó bá ṣí ibì kan, ẹnì kankan ò ní tì í; tó bá sì ti ibì kan, ẹnì kankan ò ní ṣí i.
32 Ẹni yìí máa jẹ́ ẹni ńlá,+ wọ́n á máa pè é ní Ọmọ Ẹni Gíga Jù Lọ,+ Jèhófà* Ọlọ́run sì máa fún un ní ìtẹ́ Dáfídì bàbá rẹ̀,+