Ìfihàn 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìtẹ́ mẹ́rìnlélógún (24) wà yí ká ìtẹ́ náà, mo rí àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún (24)+ tí wọ́n wọ aṣọ funfun, wọ́n jókòó sórí àwọn ìtẹ́ náà, wọ́n sì dé adé wúrà. Ìfihàn 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún+ (24) tí wọ́n jókòó sórí ìtẹ́ wọn níwájú Ọlọ́run dojú bolẹ̀, wọ́n sì jọ́sìn Ọlọ́run,
4 Ìtẹ́ mẹ́rìnlélógún (24) wà yí ká ìtẹ́ náà, mo rí àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún (24)+ tí wọ́n wọ aṣọ funfun, wọ́n jókòó sórí àwọn ìtẹ́ náà, wọ́n sì dé adé wúrà.
16 Àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún+ (24) tí wọ́n jókòó sórí ìtẹ́ wọn níwájú Ọlọ́run dojú bolẹ̀, wọ́n sì jọ́sìn Ọlọ́run,