Mátíù 24:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 torí ìpọ́njú ńlá máa wà nígbà náà,+ irú èyí tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé títí di báyìí, àní, irú rẹ̀ kò ní ṣẹlẹ̀ mọ́.+ Máàkù 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 torí àwọn ọjọ́ yẹn máa jẹ́ àwọn ọjọ́ ìpọ́njú,+ irú èyí tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀dá tí Ọlọ́run dá títí di àkókò yẹn, irú rẹ̀ kò sì ní ṣẹlẹ̀ mọ́.+
21 torí ìpọ́njú ńlá máa wà nígbà náà,+ irú èyí tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé títí di báyìí, àní, irú rẹ̀ kò ní ṣẹlẹ̀ mọ́.+
19 torí àwọn ọjọ́ yẹn máa jẹ́ àwọn ọjọ́ ìpọ́njú,+ irú èyí tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀dá tí Ọlọ́run dá títí di àkókò yẹn, irú rẹ̀ kò sì ní ṣẹlẹ̀ mọ́.+