Ìfihàn 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tí ààrá méje náà sọ̀rọ̀, mo fẹ́ kọ̀wé, àmọ́ mo gbọ́ ohùn kan láti ọ̀run+ tó sọ pé: “Gbé èdìdì lé àwọn ohun tí ààrá méje náà sọ, má sì kọ wọ́n sílẹ̀.”
4 Nígbà tí ààrá méje náà sọ̀rọ̀, mo fẹ́ kọ̀wé, àmọ́ mo gbọ́ ohùn kan láti ọ̀run+ tó sọ pé: “Gbé èdìdì lé àwọn ohun tí ààrá méje náà sọ, má sì kọ wọ́n sílẹ̀.”