Mátíù 17:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọjọ́ mẹ́fà lẹ́yìn náà, Jésù mú Pétérù, Jémíìsì àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀ dání lọ sí orí òkè kan tó ga fíofío láwọn nìkan.+ 2 A sì yí i pa dà di ológo níwájú wọn; ojú rẹ̀ tàn bí oòrùn, aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀ sì tàn yòò* bí ìmọ́lẹ̀.+
17 Ọjọ́ mẹ́fà lẹ́yìn náà, Jésù mú Pétérù, Jémíìsì àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀ dání lọ sí orí òkè kan tó ga fíofío láwọn nìkan.+ 2 A sì yí i pa dà di ológo níwájú wọn; ojú rẹ̀ tàn bí oòrùn, aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀ sì tàn yòò* bí ìmọ́lẹ̀.+