Ìfihàn 16:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìkeje sì da ohun tó wà nínú abọ́ rẹ̀ sínú afẹ́fẹ́. Lẹ́yìn náà, ohùn kan dún ketekete látinú ibi mímọ́+ níbi ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Ó ti rí bẹ́ẹ̀!”
17 Ìkeje sì da ohun tó wà nínú abọ́ rẹ̀ sínú afẹ́fẹ́. Lẹ́yìn náà, ohùn kan dún ketekete látinú ibi mímọ́+ níbi ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Ó ti rí bẹ́ẹ̀!”